Poco Lee – JOKORIKO Lyrics

Poco Lee JOKORIKO Lyrics (feat. Qdot)

Ọmọọmọ Mọriamọ (Alagbe)
Mo ki gbe

Ijo kan wa for my area
Ọwọ meji loke bi ẹni to fẹ k’hallelluyah
K’ẹsẹ rẹ ma gbọn gbọn bi ẹni to ni malaria

O jokoriko jokoriko jokori jokori jokoriko
O joriko jokoriko jokori jokori jokoriko (Change ẹ)

O joriko jokoriko jokori jokori jokoriko

Ki lo n jẹ jokoriko?
Ijo tuntun la ti Puerto Rico
Ọmọ alfa lo n fa koriko
Ọmọ pastor lo wa foriko o
Ta lo gbejo wa?
Poco ni
Ta lo gbọmọ lọ?
Poco ni
Ọmọ London ini ini
Igbo ogini gini
Yooba lo ni kini kini
Baby no kill me kill me

Ijo kan wa for my area
Ọwọ meji loke bi ẹni to fẹ k’hallelluyah
K’ẹsẹ rẹ ma gbọn gbọn bi ẹni to ni malaria

O jokoriko jokoriko jokori jokori jokoriko
O joriko jokoriko jokori jokori jokoriko (Change ẹ)
O jokoriko jokoriko jokori jokori jokoriko
O joriko jokoriko jokori jokori jokoriko

Come and sọdi sọdi bẹrẹkẹtẹ bẹrẹkẹtẹ niwaju agbalagba
Come and take banana ṣo mọ Tecno to kọ “Pana”?
I know you like Ronaldo, show me Messi, Maradona
I know you want to commando echo Roger Milla
Ṣedi ẹ bala bala bala
Ṣedi ẹ bala bala
Ṣedi ẹ bolo bolo bolo
Ṣedi ẹ bolo bolo
Jẹ ko maa twe twe twe twe