Sola Allyson – Eji Òwúrọ̀ 20 Lyrics

Sola Allyson Eji Òwúrọ̀ 20 Lyrics

Dúró tì mí o olólùfé
Ïfé tí kò l’ábükù ni ko’ bá mi lò
Dúró tì mí o olólüfé
Ifé tí kò la’bawón ni kó’ o bá mi lò

Ïfé bí eji ôwúrò
Lát’àgbàlá elédúmarè ló’ ti sè wá
Ïfé tó’ t’òrò minimini
T’ábàwón avé è kanô le è bäjé o
Olólufé férän mi la’ ïsètän

Fémibíojútin fémú
Fé mi bí irun tin f’órí
Fe mi bí ehín tiñ fé’ nu
Fe mi tèmítèmí
Fe mi tokäntokän
Fé mi taratara
Olólüfé féran mi la’ ïsètàn

Îfé bí eji ôwúrò
Lat’âgbàlá elédümarè ló’ ti sè wá
Ïfé tó’ t’ôrò minimini
T’ábâwón ayé è kan ò le è bäjé o
Olólüfé férân mi l’áïsètän
Bá mi so’ tító mo éf o toóto
Bá mi s’ôdodo mo fé o pèlú ôdodo
Bá mi sô’ tító mo éf o toótó
Bá mi s’ôdodo mo fé o pèlú ôdodo b’ógiriò bá la’nu aláñgbá ò lè w’ògiri
Eléèdá ló’ yàn wá papò èsù kò ní yà wá o

Îfé bí eji ôwúrò
Lát’àgbälá elédümarè ló’ ti sè wá
Îfé tó’ t’ôrò minimini
T’ábawón ayé èkan ôle èbäjé o
Olólüfé férän mi lá’ isètàn

Amãa l’ówó l’ówó
A m ã a b í m o l é m’ o a mãa s’ ayò má’ yò
Amãa so’ lá mó’ la
Ká’ sãàmúf’é elédümarèès lá’ïsètàno

Amãa l’ówó l’ówó
A m ã a b í m o l é m’ o a mãa s’ ayò má’ yò
A m a a s o’ l á m ó’ l a
Ká’ sãà múf’é elédümarè ès la’ ïsètàn o

Îfé bí eji ôwúrò
Lát’àgbâlá elédùmarè ló’ ti sè wá
Ïfé tó’ t’òrò minimini
Tá’ bâwón ayé èkan ôel èbäjé o
Olólüfé féran mi lá’ isètän

Gb’ámòrän mi olólüfé èmi
Olùränlówó la’ fi mí se fún o lát’örun wá
F’etí s’ámòràn mi olólüfé mi
Olùrànlówó la’ fi mí se fún o lát’ôrun wá
Ká’ jo rïn ká’ s’ògo f’órúko olórun
Alábarìn la’ fí mí es fún o lát’òrun wá
M’ókän kúrò nínú asán ayé
Ètàn ò da ñkankan fún ni

Fé atopé l’ó lè mü wa l’ayé já laïlabäwön o
M’ókàn kürò nínú asán ave
Étan o da nkankan fün ni
Ifé at’opé ló le mü wa lavé já lailábawón o

Ifé bí eji owürò
Latagbala elédümare lo ti sè wa
Ifé tó torò minimini
Tabawón aye è kan o le é bajé o
Olôlüfé férän mi laisètàn

Ololüfé férän mi laisêtàn o
Olólüfe feran mi laisetàn o

Öré okän mi ipin jò pin irin jörin la se ñ r’ irin yí o
Ololùfé féràn mi laisêtän

Ololüfé férän mi laïsètän o
Olôlüfé féran mi laisètàn o