Sola Allyson Má Mi’kan III Lyrics, Sola Allyson Má Mi’kan 3 Lyrics
Wa wole, mãa bo omo,
Ônà ïmólè yí mà dün gan
Wá je nínú adun yen o
Wá wolé
Kòs’ádün l’óde
Mãa bò omo
Ibí la’ dün wä omo
Wá je nínú adün yen o
Wá wolé
Come come mãa bò omo
Önaïmólè yí mä dün gan
Wa ej nínú adün yen o
Gbà mí gbó p’odún yí á sàn wá
P’odún yí á sàn wá
Gbà mí gbo p’odún ví á sàn wá
P’odún yí á sàn wá
Gbà mí gbó p’odún yí á sàn wá o
Igbé ayé tí mò’ñ gbé á sàn mí o
Gbà mí gbó p’odún yí á sàn wá
P’odún yí á sàn wá
Gbà mí gbó ayé yí a sàn mí o,
Ayé è yí á sàn wá o
Gbà mí gbó p’odún yí á sàn wá
P’odún yí á sàn wá
Gbà mí gbó odún yí á sàn wá
Ayé tí moñ gbé á sàn mí o
Gbà mí gbó p’odún yí á sàn wá
P’odún yí á sàn wá
Gbà mi gbó alayo m’áyò de o
Aláyo ó m’áyò dé o
Gbà mí gbó p’aláyò m’áyò dé
Alávo ó m’áyò dé
Gbà mí gbo baba aláyò m’áyò dé sínú ibanújè okän mi
Aláyò m’áyò dé o
Gbà mí gbó p’aláyò m’ávò dé
Aláyo ó m’áyo dé
Gbà mí gbó aláyò ma s’ôgo
Aláyò ma s’ògo
Gbà mí gbó p’aláyo ma s’ôgo
Aláyo ma s’ogo
Gbà mí gbó babá ológo a fi mí s’ògo
Aláyò máa s’ ôgò
Gbà mí gbó p’aláyò ma s’ôgo
Alayo ma s’ôgo
Bàbá re ló l’ôrò
Bàbá re l’ó l’oore gbogbo
Bàbá re l’ó níôgo
Bàbá re l’ó ni ôrò
Bàbá re l’ó l’oore gbogbo
Babá re l’ó ní ôgo
Om’oba má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbâgbé o
Om’ова má mi’kän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbagbé o
Om’oba má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbàgbé o
Isé t’á a rán mí sí o niyen
Om’oba má mikän
Om’oba má s’ojo
Om’oba má gbägbé o